ANNA FERRIERO (Traduzione di Debo Ajibade - Nigeria)
ÀTỌWỌ́DÁ (ỌKÀN)
Óju ko f’ẹnu kòmílẹ́nu lásán lọ
Miò tí rìí n kankan rárá
irú àwọn ènìyàn t’ólórúkọ bí tirẹ
tí ìfẹ́ wọn wuni
Mo r’ọ́gbọ́n díẹ̀ kọ́ lát’ara wọn
mo n fi ìgbà oru ṣ’àlá lá
O d’ẹnu ìfẹ́ kọ àyò mi
lálái gb’àṣẹ
Sùgbọ́n dídákẹ́ mi
jẹ́ kí n bẹ̀rẹ̀ sí ní lá àlá l’ákọ̀tun
ìwọ l’ẹni t’ọkàn mi fẹ́
ohun tí mo fẹ́ nì
ká gb’óríyìn fún òrùn t’ówọ̀ bá
olólùfẹ́ mi tuntun
VALVE
Più del tuo bacio
nulla ancora ho mai visto;
men del tuo nome
velluto d’amore
ancor poco ho imparato.
Sogno d’estate
corteggi il mio verso
senza un consenso
ma giace in silenzio.
Sogno già nuovo
sta il mio verso cantando
che rinasce in quel rosso
donando tramonto
al nuovo mio inchiostro
YAKOMÓSÌ
Ìmísí ọ̀tun
di ìkún omi
nínú ayé mi láì d’áwọ́ dúró
òṣùpá olóǒrùn didun
àṣẹ̀sẹ̀yọ
tó dúró gidigba
Wọ́n ṣ’ẹ̀fẹ̀ pẹ̀lú ore-ọ̀fẹ́
t’ọ̀yàyà t’ọ̀yàyà
Óku wákàtí kan tí oòrùn yóò fi wọ̀
Nígbàtí omi òkun k’órajọ
ówà ni dìdákẹ́jẹ́
ìrètí t’óga
Gbogbo ohun t’óní àwọ̀ búlù
l’ófi s’ẹ̀ṣọ́ l’ákọ̀tun
Fàájì bẹ̀rẹ̀ ní pẹreru
Àsìkò ìgbádùn l’awà yí
wúrà, búlùu pẹ̀lú àwọ̀ tọ́kọ́ìsì
láti ara ẹja-òkun t’ówà ní ẹ̀gbẹ́ òkun
t’ówà láàrin Ésíà àti díẹ̀ lápá Yúróòpù
wọ́n f’arahàn l’áàlà, pẹ̀lú ìṣọ̀kan
èyí t’ófún wa ní ìran ọ̀tun, ohun tí gbogbo àgbáyé ún rètí
ìrìnàjò t’óyàtọ̀ gédéngbé
àdáyébá àgbá-omi kékeré àtinúwá ìgbéjasí
láti máa wà láàyè ní gbogbo ìgbà
pẹ̀lú ìfẹ́ t’ójinlẹ̀
tó pààlà pẹ̀lú ìlà-oòrùn
ìtàn òjìji òṣùpá
óhún dán gbinrin l’ákọ̀tun
nígbà t’óṣùpá t’ókún nìkan
bá ún dájó láàrín agbo òṣèré
YAKAMOZ
Nuova ispirazione,
inonda,
la mia vita senza sosta
profumi di luna,
nascenti,
di soppiatto
scherzano con garbo,
in entusiasmo
un’ora prima del tramonto
quando il mare si richiude
con silenzio e grande attesa:
tutto in blu si ridecora.
Lo spettacolo si schiude,
è l’ora della festa
oro, blu e turchese
dai gabbiani in riva al mare
fra l’Asia e un po’ d’Europa
si riflettono al confine,
in armonia
regalando un nuovo sogno, speranza mondiale
d’un viaggio eccezionale,
un acquario naturale
per vivere ogni volta,
con l’amore ancor profondo
sfiorando verso Oriente
il riflesso della luna,
nuova nota scintillante
quando il solo plenilunio
nell’orchestra può danzare
AWỌ ARA
Ìmọ́lẹ̀
tó tàn nípasẹ̀ b’órìṣà ìfẹ́ ṣe n wò
Ríró ìgbì omi òkun
tó n dún bí ìgbà ènìyàn bá n mí
Àtúnbí
nípa òògùn ara ìkarahun
Ìfẹnukonu
aláìnítìjú ẹlẹ̀tàn
ó ndán gbinrin bíi sányán
adùn fí f’ọwọ́ kanni rẹ̀ nipé
ìf’ọwọ́pa l’ára rẹ̀
n’ítumọ̀
bi aṣọ àrán tó jííre
PELLE
Luce
attraverso lo sguardo smeraldo
Onde
attraverso il respiro sonoro
Rinascita
attraverso il sudor di conchiglia
Bacio
timido adulatore
setoso
il dolce suo tocco
in carezza marina
profondo
in velluto dipinto
ÌBÒJI MI
Oju ìfẹ́
níbi ìtàsán òrùn d’ojú kọ
láàrín àwọn bèbè ìtẹ́lẹ̀ ojú
tó dàbí àwọ̀ erùpẹ̀
t’ótún gbé awọ Búlákìbẹrì wọ̀
iyebíye ni – ósì tún wuyì jọjọ
tó ṣe fifún olùrékọjá lọ
ẹwà àsìkò ìgbà oru
tó ládùn púpọ̀
ohun àmúyangàn obìnrin
tó nṣe àfihàn ìrọ̀lẹ̀ ayé
tó f’arasin
s’ínú òróró ara òhun oje ọyàn
kálàmù alagbalúgbú omi
tó jẹ́
olórí kunkun t’ótún j’ojú nígbèsè
wọ́n kọ ogunlọ́gọ̀
ayígbiri ìfẹnukonu ìfẹ́
t’ówà láàrín ìkarahun lásán àti ẹwà labalábá
LA MIA SFUMATURA
Viso d'amore
dove un raggio si affaccia
fra le rive degli occhi
color della sabbia.
Pelle di mora
preziosa - elegante
che dona al passante
d'estate bellezza
d'immensa dolcezza.
Grazia di donna
al tramonto si specchia
avvolta soltanto
da note agrumate
d'inchiostro del mare
che
ribelli e sognanti
scrivono onde
di ritmi baciati
fra conchiglie e farfalle
(Traduzione di Debo Ajibade - Nigeria)